ORIKÍ DE EXÚ
Èsù òta òrìsà.
Exú, o inimigo dos orixás.
Osétùrá ni oruko bàbá mò ó.
Osétùrá é o nome pelo qual você é chamado por seu pai.
Alágogo Ìjà ni orúko ìyá npè é,
Alágogo Ìjà é o nome pelo qual você é chamado por sua mãe.
Èsù Òdàrà, omokùnrin Ìdólófin,
Exú Òdàrà, o homem forte de ìdólófin,
O lé sónsó sí orí esè elésè
Exú, que senta no pé dos outros.
Kò je, kò jé kí eni nje gbé mì,
Que não come e não permite a quem está comendo que engula o alimento.
A kìì lówó láì mú ti Èsù kúrò,
Quem tem dinheiro, reserva para Exú a sua parte,
A kìì lóyò láì mú ti Èsù kúrò,
Quem tem felicidade, reserva para Exú a sua parte.
Asòntún se òsì láì ní ítijú,
Exú, que joga nos dois times sem constrangimento.
Èsù àpáta sómo olómo lénu,
Exú, que faz uma pessoa falar coisas que não deseja.
O fi okúta dípò iyò.
Exú, que usa pedra em vez de sal.
Lóògemo òrun, a nla kálù,
Exú, o indulgente filho de Deus, cuja grandeza se manifesta em toda parte.
Pàápa-wàrá, a túká máse sà,
Exú, apressado, inesperado, que quebra em fragmentos que não se poderá juntar novamente,
Èsù máse mí, omo elòmíràn ni o se.
Exú, não me manipule, manipule outra pessoa.
ORIKÍ DE OGUM
Ògún laka aye
(Ogun poderoso do mundo)
Osinmole
(O próximo a Deus)
Olomi nile fi eje we
(Aquele que tem água em casa, mas prefere banho com sangue)
Olaso ni le
(Aquele que tem roupa em casa)
Fi imo bora
(Mas prefere se cobrir de mariô)
La ka aye
(Poderoso do mundo)
Moju re
(Eu o saúdo)
Ma je ki nri ija re
(Que eu não depare com sua ira)
Iba Ògún
(Eu saúdo Ogun)
Iba re Olomi ni le fi eje we
(Eu o saúdo, aquele que tem água em casa, mas prefere banho de sangue)
Feje we. Eje ta sile. Ki ilero
(Que o sangue caia no chão para que haja paz e tranquilidade)
Ase
Axé
ORIKÍ DE EWÁ
Ejo Ejo Ewà
(cobra , cobra é Ewà)
Idã Idã Ewà
Ewà ô
(salve Ewà)
Ossumarè olowo gbanigbà
( salve Ossumarè dono das riquezas imensas)
Ossumarè o njo nile
(Ossumarè está dançando em nossa casa)
Ewá yá mi orissà njo nile Ossumarè
( minha mãe Ewà está dançando com Ossumarè em nossa casa)
Ewà ô
(salve Ewá)
Ewà Ibà re ô
(Ewá nós te saudamos)
Ewà mojubà
(Ewá seja benvinda)
Ewà ja mi, ko kerè, ko kerè
( nossa mãe Ewà não é pequena)
Orubatà!
( ela é imensa)
ORIKÍ DE YANSÃ
Oyà A To Iwo Efòn Gbé.
Ela é grande o bastante para carregar o chifre do búfalo.
Oyà Olókò Àra.
Oyà, que possui um marido poderoso.
Obìnrin Ogun,
Mulher guerreira.
Obìnrin Ode.
Mulher caçadora.
Oya Òrírì Arójú Bá Oko Kú.
Oyà, a charmosa, que dispõe de coragem para morrer com seu marido.
Iru Èniyàn Wo Ni Oyà Yí N Se, Se?
Que tipo de pessoa é Oyà?
Ibi Oya Wà, Ló Gbiná.
O local onde Oyà está pega fogo.
Obìnrin Wóò Bi Eni Fó Igbá.
Mulher que se quebra ao meio como se fosse uma cabaça
Oyà tí awon òtá rí,
Oyà foi vista por seus inimigos
Tí Won Torí Rè Da Igbá Nù Sì Igbó.
E eles, assustados, fugiram atirando as bagagens no mato.
Héèpà Héè, Oya ò!
Eeepa He! Oh, Oyà!
Erù Re Nikan Ni Mo Nbà O.
És a única pessoa que temo.
Aféfé Ikú.
Vendaval da Morte
Obìnrin Ogun, Ti Ná Ibon Rè Ní À Ki Kún
A mulher guerreira que carrega sua arma de fogo
Oyà ò, Oyà Tótó Hun!
Oh, Oyà, à Oyà respeito e submissão!
Oyà, A P’Agbá, P’Àwo Mó Ni Kíákíá,
Ela arruma suas coisas sem demora
Kíákíá, Wéré Wéré L’ Oyà Nse Ti È
Rapidamente Oyà faz suas coisas
A Rìn Dengbere Bíi Fúlàní.
Ela vagueia com elegância, como se fosse uma nômade fulani.
O Titi Tí Nfi Gbogbo Ará Rìn Bí Esin
Quando anda, sua vitalidade é como a do cavalo que trota.
Héèpà, Oya Olómo Mesan, Ibá Re Ò!
Eeepa Oya, que tem nove filhos, eu te saúdo!
ORIKÍ DE OXUMARÊ
Osumare A Gbe Orun Li Apa Ira
Osumare permanece no Céu que ele atravessa com o braço
Ile Libi Jin Ojo
Ele faz a chuva cair na terra.
O Pon Iyun Pon Nana
Ele busca os corais, ele busca as contas nana
O Fi Oro Kan Idawo Luku Wo
Com uma palavra ele examina Luku
O Se Li Oju Oba Ne
Ele faz isso perante seu rei
Oluwo Li Awa Rese Mesi Eko Ajaya
Chefe a quem adoramos
Baba Nwa Li Ode Ki Awa Gba Ki
O pai vem ao pátio para que cresçamos e tenhamos vida
A Pupo Bi Orun
Ele é vasto como o céu
Olobi Awa Je Kan Yo
Senhor do Obi, basta a gente comer um deles para ficar satisfeito
O De Igbo Kùn Bi Ojo
Ele chega à floresta e faz barulho como se fosse a chuva
Okó Ijoku Igbo Elu Ko Li Égùn
Esposo de Ijo, a mata de anil não tem espinhos
Okó Ijoku Dudu Oju E A Fi Wo Ran
Esposo de Ijoku, que observa as coisas com seus olhos negro.
ORIKÍ DE OXÓSSI
Oxóssi
Awo odé ìjà pìtìpà.
Omo ìyá ogum oníré.
Oxóssi gbà mí o.
Orixá a dínà má yà.
Ode tí nje orí eran.
Eléwà òsòòsò.
Orixá tí ngbélé imò,
gbé ilé ewé.
A bi àwò lóló.
Oxóssi kì nwo igbó,
Kí igbo má mì tìtì.
Ofà ni mógàfí ìbon.
O ta ofà sí iná
Iná kú pirá.
O tá ofà sí Oòrùn,
Oòrùn rè wèsè.
Ogbàgbà tí ngba omo rè.
Oní màrìwò pákó.
ODE BÀBÁ Ò,
O DÉ OJÚ OGUN,
O FI OFÀ KAN SOSO PA IGBA ÈNÌYÀN.
ODÉ NÍ IGBÓ,
O FI OFÀ KAN SOSO PA IGBA ERANKO.
AWO ERAN PA SÍ OJÚBO ÒGÚN LÁKAYÉ.
MÁ WO MÍ PA O !
MÁ SÌ FI OFÀ OWO RE DÁ MI LÓRÓ.
ODE Ò, ODE Ò, ODE Ò !
ÒSÓÒSÌ NI NBÁ ÒDE INÚ IGBO JÀ,
WÍPÉ KÍ Ó DE IGBÓ RE.
ÒBÁ AJÉ JÀ,
O SÉGUN.
ÒSÓÒSÌ O !
ÒSÓÒSÌ OLORÓ TI NBÁ OBA SÉGUN
ÒBÁ AJÉ JÀ,
O SÉGUN.
ÒSÓÒSÌ O!
MÁ BÀ MI JÀ O .
OGUN NI O BÁ MI SE O .
BÍ O BÁ NBÒ LÁTI OKO, KÓ O RE ÌRÉRÉ ÌDÍ RÈ.
MÁ GBÀBÉ MI O,
ODE Ò, BÀBÁ OMO KÍ NGBÀBÉ OMO.
ÀSE, ÀSE, ÀSE.
Ouça abaixo o áudio do ingôrôssi de Oxóssi muito usado nos candomblés de nação angola e outras nações para atrair muita fartura e prosperidade.
ORIKÍ DE XANGÔ
Sángiri-làgiri,
Olàgiri-kàkààkà-kí Igba Edun Bò
O Jajú Mó Ni Kó Tó Pa Ni Je
Ó Ké Kàrà, Ké Kòró
S' Olórò Dí Jínjìnnì
Eléyinjú Iná
Abá Won Jà Mà Jèbi
Iwo Ní Mo Sá Di O
Sango Ona Mogba Bi E Tu Bá Wó Ile
Jejene Ni Mú Ewure
Bi Sango Bá Wó Ile
Jejene Ni Mú Osa Gbogbo
ORIKÍ DE OSSÃE
Agbénigi, òròmodìe abìdi sónsó
Esinsin abedo kínníkínni;
Osanyin a ri ibi ri ohun.
Bi Eledumare.
Alase Ewé. Osanyin!
Nibo ni Orunmilá nló ti ko mú Exu dani.
Nibo ni Orunmilá nló ti ko mú Osanyin dani.
Aroni elese kan xoxo.
Babá ni alaxé ewe fun Orunmilá ati gbogbo awon okanlenigba imalé.
Aképè nigbà òràn kò sunwòn
Elésè kan jù elésè méjì lo.
A niyi kaye bi Eledumare
Agba axé |Ogun ta gie-gie
Aroni elese kan ti o gba olokunrun kalé.
Bi Eni gbe omodé. Aro obi-oko lielie.
Ewe o, ewe o, ewe o! A npé o, wa jé wa ooo.
Omo awo ni nxé Oogun. Osanyin wa jé wá.
ORIKÍ YÁMI OXORONGÁ
Okiti Kata, Ekùn A Pa Eran Má Ni Yan
Olu Gbongbo Ki Osun Ebi Ejè
Gosun-gosun On Wo Ewu Ejè
Ko Pá Eni Ko Je Oka Odun
A Ni Esin O Ni Kange
Odo Bara Oto lu
Omi a Dake Je Pa Eni
Omo Opara Oga Ndanu, Sese Iba o !
Iba Ìyàmì o !
NiMo Mo Je Ni Ko Je Ti Aruní
Emi Wa Foribale Fun Sese
Olu idu Pe O papa
Ele Adie Ko Tuka
IyaTemi Mi Ni Bariba Li Akoko
Emi Ako Ni Ala Mo Le Gbe Agada
Emi A Wa Kiyà Onile Ki Ile.
Ìbà Ìyàmì o !
Asé O !
ORIKÍ DE LOGUN-ODÉ
ORIKÍ DE NANÃ
Okiti Kata, Ekùn A Pa Eran Má Ni Yan
Olu Gbongbo Ko Sun Ebi Eje
Gosungosun On Wo Ewu Eje
KO Pá Eni Ko Je Oka Odun
A Ni Esin O Ni Kange
Odo Bara Otolu
Omi a Dake Je Pa Eni
Omo Opara Ogan Ndanu
Sese Iba O
Iba Iye Ni Mo Mo Je Ni Ko Je Ti Aruní
Emi Wa Foribale Fun Sese
Oluidu Pe O papa
Ele Adie Ko Tuka
Yeye Mi Ni Bariba Li Akoko
Emi Ako Ni Ala Mo Le Gbe Agada
Emi A Wa Kiyà Onile Ki Ile