• WhatsApp:
  • (33) 9.9946-1734

Portuguese English Spanish

ORIKÍ  DE  OXÓSSI

 

Oxóssi
Awo odé ìjà pìtìpà.
Omo ìyá ogum oníré.
Oxóssi gbà mí o.
Orixá a dínà má yà.
Ode tí nje orí eran.
Eléwà òsòòsò.
Orixá tí ngbélé imò,
gbé ilé ewé.
A bi àwò lóló.
Oxóssi kì nwo igbó,
Kí igbo má mì tìtì.
Ofà ni mógàfí ìbon.
O ta ofà sí iná
Iná kú pirá.
O tá ofà sí Oòrùn,
Oòrùn rè wèsè.
Ogbàgbà tí ngba omo rè.
Oní màrìwò pákó.
ODE BÀBÁ Ò,
O DÉ OJÚ OGUN,
O FI OFÀ KAN SOSO PA IGBA ÈNÌYÀN.
ODÉ NÍ IGBÓ,
O FI OFÀ KAN SOSO PA IGBA ERANKO.
AWO ERAN PA SÍ OJÚBO ÒGÚN LÁKAYÉ.
MÁ WO MÍ PA O !
MÁ SÌ FI OFÀ OWO RE DÁ MI LÓRÓ.
ODE Ò, ODE Ò, ODE Ò !
ÒSÓÒSÌ NI NBÁ ÒDE INÚ IGBO JÀ,
WÍPÉ KÍ Ó DE IGBÓ RE.
ÒBÁ AJÉ JÀ,
O SÉGUN.
ÒSÓÒSÌ O !
ÒSÓÒSÌ OLORÓ TI NBÁ OBA SÉGUN
ÒBÁ AJÉ JÀ,
O SÉGUN.
ÒSÓÒSÌ O!
MÁ BÀ MI JÀ O .
OGUN NI O BÁ MI SE O .
BÍ O BÁ NBÒ LÁTI OKO, KÓ O RE ÌRÉRÉ ÌDÍ RÈ.
MÁ GBÀBÉ MI O,
ODE Ò, BÀBÁ OMO KÍ NGBÀBÉ OMO.
ÀSE, ÀSE, ÀSE.

 

Ouça abaixo o áudio do ingôrôssi de Oxóssi muito usado nos candomblés de nação angola e outras nações para atrair muita fartura e prosperidade.

 

 

Compartilhar nas redes sociais

  • Radio Nocaute ao vivo::